Download Motunrayo Adewoyin – Awamaridi

Artist(s) Name:

Track Title: Awamaridi

Category: Music, Lyrics

Output Format: audio mp3

Published: 2022

Motunrayo Adewoyin Awamaridi mp3 download
Motunrayo Adewoyin introduces another new song titled “Awamaridi” and it’s here for quick download.

Gospel music phenomenally enormous singer Motunrayo Adewoyin drops in a new track titled “Awamaridi”.

Download Mp3

Lyrics: Motunrayo Adewoyin – Awamaridi

Iba’koda aye
Iba’seda orun
Iba’koda aye
Iba’seda orun
Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya
Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya

Iba’koda aye
Iba’seda orun
Iba’koda aye
Iba’seda orun
Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya
Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya

E wole f’oba, Ologo julo
E korin ipa ati ife Re
Alabo wa ni, at’Eni igbani
O ngbe ‘nu ogo Eleru ni iyin

Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya
Oke nla ti n ka satani laya o,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya

Eru re n ba mi o,
Mo’laya re n pa mi.
Eru re n ba mi o,
Aya re n pa mi.
Awamaridi eledumare, oba mi toto fi’se ogun ran
Awamaridi eledumare, baami atonigba.

Eru re n ba mi o,
Mo’laya re n pa mi.
Eru re n ba mi o,
Aya re n pa mi.
Awamaridi eledumare, oba mi toto fi’se ogun ran
Awamaridi eledumare, baami atonigba o.

Awamaridi eledumareee, eni nla toto fi’se ogun ran
Awamaridi eledumare, baami atonigba o.
Awaaa…..maridi…… eni toto fi’se ogun ran
Awa a ko ridi re o, baami atonigba o.
Awaaa…..o eni toto fi’se ogun ran
Awa, ao ridi re o, baami atonigba o.